Lyrics Olúmọ Brymo

highque 0

Mò n lọ sáké mo fẹ́ lọ rọ́jọ̀gbọ́n o Mò n lọ sábéòkúta mo fé lọ rí Ọmọ ṣóyínká

Oṣóyinká ooooo Oṣóyinká Oṣóyinká ooooo Bẹ lọ sówu Bẹ bá rárẹ̀mú o Bẹ bá rí bába Ìyábọ̀, ẹ bá mi ki Ẹbọra òwu Ẹbọra òwu ooooo Ẹbọra òwu, eh Ẹbọra òwu ooooo Bẹ lọ sábẹ́òkúta ìlú olúmọ Bẹ bá ráláké ẹ bá mi ki

 

Download Here

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *